Learn and Speak languages with native speakers

Olukọ Gẹẹsi ayelujara

Kọ Gẹẹsi lori ayelujara pẹlu Olukọ Gẹẹsi to wa lati ilu Gẹẹsi tabi Amẹrika


O lee gba ekọ  edeGẹẹsi mẹta lofẹẹ lori ayelujara, fi orukọ rẹ silẹ lonii, ko nilo lati ra nkankan, ko nilo káàdi ìsanwó, ọfẹ ni lootọ!

Kikọ Gẹẹsi
le ṣoro nitori eyi ni o ṣe nilo lati ni ìtọnisọna to dára.


O nilo Olukọ Gẹẹsi lori ayelujara ti o le gbójúlé. O nilo Olukọ Gẹẹsi onílu ti yo kọjúmọ ìwọ nìkan. Igbésẹ ìkíní ni lati ṣàwári ẹni tí o le ṣiṣẹ nà.
Awọn kan lero wipe igba to nilo Olukọ Gẹẹsi nikan ni  bi o ba n ṣe idanwo bíi  IELTS, CAE tàbí TOEFL. Eyinni kò ri bẹẹ rara.  Olukọ Gẹẹsi onílu lori ayelujara tó mọ ede le fun ọ ni iranlọwọ to yẹ nígbàtí o ba nkọ èdè gírámà ati ọrọ amulo ojoojumọ to ta koko. Awọn ẹkọ yi ni a o ma kọ ọ nipasẹ eto Olukọ kan-sí-akẹkọ kan nibi ti iwọ yo ti ni afojusun nipasẹ akọṣẹmọṣẹ lati mu ọ ni imọ ati dagba.
Ede Gẹẹsi le takoko lati mọ, awọn ohun kọọkan ti o jẹ wipe akọṣẹmọṣẹ Olukọ Gẹẹsi lo le ye. Ọrọ sisọpọ ati ibanisọrọ pẹlu Olukọ èdè Gẹẹsi ṣe pàtàkì fun idagbasokè rẹ gẹgẹ bi akẹkọọ.

Olukọ Gẹẹsi ayelujara


Ni Lingostan, oriṣiriṣi awọn akọṣẹmọṣẹ Olukọ ti wọn funni ni ẹkọ Gẹẹsi lori Skype.Eyi tumọ si pe o ko nilo lati fi ile rẹ silẹ ki o to kọ nipa Gẹẹsi gba ọwọ akọṣẹmọṣẹ. Eyi tun tumọsi pe o ko ni lati na owo danu lori ẹkọ Gẹẹsi pelu owo to gara. Iwọ lo maa mu akoko, ọjọ ati wipe o le ṣawari awọn Olukọ ti owo wọn ba apo rẹ mu. Oriṣiriṣi anfani lo wa fun ọ gẹgẹ bi akẹkọọ ede ti ko si fun awon ilana ẹkọ Gẹẹsi kikọ miran lori wẹẹbu ayelujara.
Bẹẹrẹ loni pẹlu eto ẹkọ, safikun imo ede Gẹẹsi re pẹlu awon Olukọ Gẹẹsi lori ayelujara. To awon eniyan rẹ papọ, pade eniyan titun ati wipe o tun le pa owo nipasẹ eyi.